2 Sámúẹ́lì 17:17 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 17 Jónátánì+ àti Áhímáásì+ ń gbé ní Ẹ́ń-rógélì;+ ìránṣẹ́bìnrin kan lọ sọ ohun tó ṣẹlẹ̀ fún wọn, àwọn náà sì lọ sọ fún Ọba Dáfídì, nítorí ẹnikẹ́ni ò gbọ́dọ̀ rí wọn pé wọ́n wọnú ìlú.
17 Jónátánì+ àti Áhímáásì+ ń gbé ní Ẹ́ń-rógélì;+ ìránṣẹ́bìnrin kan lọ sọ ohun tó ṣẹlẹ̀ fún wọn, àwọn náà sì lọ sọ fún Ọba Dáfídì, nítorí ẹnikẹ́ni ò gbọ́dọ̀ rí wọn pé wọ́n wọnú ìlú.