2 Sámúẹ́lì 8:16 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 16 Jóábù+ ọmọ Seruáyà ni olórí àwọn ọmọ ogun, Jèhóṣáfátì+ ọmọ Áhílúdù sì ni akọ̀wé ìrántí. 2 Sámúẹ́lì 20:23 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 23 Nígbà náà, Jóábù ni olórí gbogbo àwọn ọmọ ogun Ísírẹ́lì;+ Bẹnáyà+ ọmọ Jèhóádà+ sì jẹ́ olórí àwọn Kérétì àti àwọn Pẹ́lẹ́tì.+ 1 Àwọn Ọba 1:5 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 5 Ní àkókò yìí, Ádóníjà+ ọmọkùnrin Hágítì ń gbé ara rẹ̀ ga, ó ń sọ pé: “Èmi ló máa di ọba!” Ó ní kí wọ́n ṣe kẹ̀kẹ́ ẹṣin kan fún òun, ó kó àwọn agẹṣin jọ àti àádọ́ta (50) ọkùnrin tí á máa sáré níwájú rẹ̀.+ 1 Àwọn Ọba 1:7 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 7 Ó lẹ̀dí àpò pọ̀ pẹ̀lú Jóábù ọmọ Seruáyà àti àlùfáà Ábíátárì,+ wọ́n ran Ádóníjà lọ́wọ́, wọ́n sì tì í lẹ́yìn.+
23 Nígbà náà, Jóábù ni olórí gbogbo àwọn ọmọ ogun Ísírẹ́lì;+ Bẹnáyà+ ọmọ Jèhóádà+ sì jẹ́ olórí àwọn Kérétì àti àwọn Pẹ́lẹ́tì.+
5 Ní àkókò yìí, Ádóníjà+ ọmọkùnrin Hágítì ń gbé ara rẹ̀ ga, ó ń sọ pé: “Èmi ló máa di ọba!” Ó ní kí wọ́n ṣe kẹ̀kẹ́ ẹṣin kan fún òun, ó kó àwọn agẹṣin jọ àti àádọ́ta (50) ọkùnrin tí á máa sáré níwájú rẹ̀.+
7 Ó lẹ̀dí àpò pọ̀ pẹ̀lú Jóábù ọmọ Seruáyà àti àlùfáà Ábíátárì,+ wọ́n ran Ádóníjà lọ́wọ́, wọ́n sì tì í lẹ́yìn.+