Diutarónómì 2:30 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 30 Àmọ́ Síhónì ọba Hẹ́ṣíbónì kò jẹ́ ká kọjá, torí Jèhófà Ọlọ́run rẹ gbà á láyè pé kó ṣorí kunkun,+ kí ọkàn rẹ̀ sì le, kó lè fi í lé ọ lọ́wọ́ bó ṣe rí báyìí. + 2 Kíróníkà 25:20 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 20 Ṣùgbọ́n Amasááyà ò gbọ́,+ torí pé látọ̀dọ̀ Ọlọ́run tòótọ́ ni èyí ti wá kí ó lè fi wọ́n lé ọ̀tá lọ́wọ́,+ nítorí pé wọ́n sin àwọn ọlọ́run Édómù.+
30 Àmọ́ Síhónì ọba Hẹ́ṣíbónì kò jẹ́ ká kọjá, torí Jèhófà Ọlọ́run rẹ gbà á láyè pé kó ṣorí kunkun,+ kí ọkàn rẹ̀ sì le, kó lè fi í lé ọ lọ́wọ́ bó ṣe rí báyìí. +
20 Ṣùgbọ́n Amasááyà ò gbọ́,+ torí pé látọ̀dọ̀ Ọlọ́run tòótọ́ ni èyí ti wá kí ó lè fi wọ́n lé ọ̀tá lọ́wọ́,+ nítorí pé wọ́n sin àwọn ọlọ́run Édómù.+