2 Kíróníkà 25:14 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 14 Ṣùgbọ́n, nígbà tí Amasááyà dé láti ibi tó ti lọ pa àwọn ọmọ Édómù, ó mú àwọn ọlọ́run àwọn ọmọ Séírì wá, ó sì gbé wọn kalẹ̀ gẹ́gẹ́ bí àwọn ọlọ́run fún ara rẹ̀,+ ó bẹ̀rẹ̀ sí í forí balẹ̀ níwájú wọn, ó sì ń mú ẹbọ rú èéfín sí wọn.
14 Ṣùgbọ́n, nígbà tí Amasááyà dé láti ibi tó ti lọ pa àwọn ọmọ Édómù, ó mú àwọn ọlọ́run àwọn ọmọ Séírì wá, ó sì gbé wọn kalẹ̀ gẹ́gẹ́ bí àwọn ọlọ́run fún ara rẹ̀,+ ó bẹ̀rẹ̀ sí í forí balẹ̀ níwájú wọn, ó sì ń mú ẹbọ rú èéfín sí wọn.