Sáàmù 3:7 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 7 Dìde, Jèhófà! Gbà mí sílẹ̀,+ ìwọ Ọlọ́run mi! Nítorí wàá gbá gbogbo àwọn ọ̀tá mi ní páárì ẹ̀rẹ̀kẹ́;Wàá ká eyín àwọn ẹni burúkú.+ Òwe 24:21, 22 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 21 Ọmọ mi, bẹ̀rù Jèhófà àti ọba.+ Má sì bá àwọn oníyapa* kẹ́gbẹ́.+ 22 Nítorí àjálù wọn yóò dé lójijì.+ Ta ló mọ ìparun tí àwọn méjèèjì* máa mú bá wọn?+
7 Dìde, Jèhófà! Gbà mí sílẹ̀,+ ìwọ Ọlọ́run mi! Nítorí wàá gbá gbogbo àwọn ọ̀tá mi ní páárì ẹ̀rẹ̀kẹ́;Wàá ká eyín àwọn ẹni burúkú.+
21 Ọmọ mi, bẹ̀rù Jèhófà àti ọba.+ Má sì bá àwọn oníyapa* kẹ́gbẹ́.+ 22 Nítorí àjálù wọn yóò dé lójijì.+ Ta ló mọ ìparun tí àwọn méjèèjì* máa mú bá wọn?+