Òwe 20:2 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 2 Ẹ̀rù* tó wà lára ọba dà bí ìgbà tí kìnnìún* bá ń kùn;+Ẹnikẹ́ni tó bá mú un bínú ń fi ẹ̀mí ara rẹ̀ wewu.+
2 Ẹ̀rù* tó wà lára ọba dà bí ìgbà tí kìnnìún* bá ń kùn;+Ẹnikẹ́ni tó bá mú un bínú ń fi ẹ̀mí ara rẹ̀ wewu.+