2 Sámúẹ́lì 8:16 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 16 Jóábù+ ọmọ Seruáyà ni olórí àwọn ọmọ ogun, Jèhóṣáfátì+ ọmọ Áhílúdù sì ni akọ̀wé ìrántí. 2 Sámúẹ́lì 18:2 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 2 Dáfídì wá fi ìdá mẹ́ta àwọn èèyàn náà sábẹ́ àṣẹ* Jóábù,+ ó fi ìdá mẹ́ta sábẹ́ àṣẹ Ábíṣáì+ ọmọ Seruáyà,+ ẹ̀gbọ́n Jóábù, ó sì wá fi ìdá mẹ́ta sábẹ́ àṣẹ Ítáì+ ará Gátì. Ọba sọ fún àwọn ọkùnrin náà pé: “Èmi náà á bá yín lọ.”
2 Dáfídì wá fi ìdá mẹ́ta àwọn èèyàn náà sábẹ́ àṣẹ* Jóábù,+ ó fi ìdá mẹ́ta sábẹ́ àṣẹ Ábíṣáì+ ọmọ Seruáyà,+ ẹ̀gbọ́n Jóábù, ó sì wá fi ìdá mẹ́ta sábẹ́ àṣẹ Ítáì+ ará Gátì. Ọba sọ fún àwọn ọkùnrin náà pé: “Èmi náà á bá yín lọ.”