ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍNTÁNẸ́Ẹ̀TÌ ti Watchtower
ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍŃTÁNẸ́Ẹ̀TÌ
ti Watchtower
Yorùbá
ọ́
  • ẹ
  • ọ
  • ṣ
  • ń
  • ẹ́
  • ẹ̀
  • ọ́
  • ọ̀
  • BÍBÉLÌ
  • ÌTẸ̀JÁDE
  • ÌPÀDÉ
  • 2 Sámúẹ́lì 17:25
    Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
    • 25 Ábúsálómù fi Ámásà+ sí ipò Jóábù+ láti máa darí àwọn ọmọ ogun; Ámásà jẹ́ ọmọ ọkùnrin kan tí orúkọ rẹ̀ ń jẹ́ Ítírà, ọmọ Ísírẹ́lì ni Ítírà, òun ló ní ìbálòpọ̀ pẹ̀lú Ábígẹ́lì+ ọmọ Náháṣì, arábìnrin Seruáyà, ìyá Jóábù.

  • 2 Sámúẹ́lì 19:13
    Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
    • 13 Kí ẹ sọ fún Ámásà+ pé, ‘Ṣebí ẹ̀jẹ̀* mi ni ọ́? Torí náà, kí Ọlọ́run fìyà jẹ mí gan-an tí o kò bá ní di olórí ọmọ ogun mi láti òní lọ dípò Jóábù.’”+

  • 1 Kíróníkà 2:17
    Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
    • 17 Ábígẹ́lì bí Ámásà,+ bàbá Ámásà sì ni Jétà ọmọ Íṣímáẹ́lì.

Yorùbá Publications (1987-2025)
Jáde
Wọlé
  • Yorùbá
  • Fi Ráńṣẹ́
  • Èyí tí mo fẹ́ràn jù
  • Copyright © 2025 Watch Tower Bible and Tract Society of Pennsylvania
  • Àdéhùn Nípa Lílò
  • Òfin
  • Ètò Nípa Ìsọfúnni Rẹ
  • JW.ORG
  • Wọlé
Fi Ráńṣẹ́