-
Jóṣúà 18:21Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
-
-
21 Àwọn ìlú ẹ̀yà Bẹ́ńjámínì ní ìdílé-ìdílé nìyí: Jẹ́ríkò, Bẹti-hógílà, Emeki-késísì,
-
-
Jóṣúà 18:25Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
-
-
25 Gíbíónì,+ Rámà, Béérótì,
-
-
Jóṣúà 21:8Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
-
-
8 Bí àwọn ọmọ Ísírẹ́lì ṣe fi kèké pín àwọn ìlú yìí àtàwọn ibi ìjẹko wọn fún àwọn ọmọ Léfì nìyẹn, bí Jèhófà ṣe pa á láṣẹ nípasẹ̀ Mósè.+
-