Ẹ́kísódù 19:5 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 5 Tí ẹ bá ṣègbọràn sí ohùn mi délẹ̀délẹ̀, tí ẹ sì pa májẹ̀mú mi mọ́, ó dájú pé ẹ ó di ohun ìní mi pàtàkì* nínú gbogbo èèyàn,+ torí gbogbo ayé jẹ́ tèmi.+ Diutarónómì 32:9 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 9 Torí àwọn èèyàn Jèhófà ni ìpín+ rẹ̀;Jékọ́bù ni ogún+ rẹ̀.
5 Tí ẹ bá ṣègbọràn sí ohùn mi délẹ̀délẹ̀, tí ẹ sì pa májẹ̀mú mi mọ́, ó dájú pé ẹ ó di ohun ìní mi pàtàkì* nínú gbogbo èèyàn,+ torí gbogbo ayé jẹ́ tèmi.+