30 “‘Kí ẹ tó pa ẹnikẹ́ni tó bá pa èèyàn,* àwọn èèyàn gbọ́dọ̀ jẹ́rìí sí i* pé apààyàn+ ni; àmọ́ ẹ má pa ẹnikẹ́ni* tó bá jẹ́ pé ẹnì kan péré ló jẹ́rìí+ sí i.
33 “‘Ẹ má sọ ilẹ̀ tí ẹ̀ ń gbé di ẹlẹ́gbin, torí ẹ̀jẹ̀ máa ń sọ ilẹ̀+ di ẹlẹ́gbin, kò sì sí ètùtù fún ẹ̀jẹ̀ tí ẹnì kan ta sórí ilẹ̀ àyàfi ẹ̀jẹ̀ ẹni náà tó ta á sílẹ̀.+