2 Sámúẹ́lì 5:17 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 17 Nígbà tí àwọn Filísínì gbọ́ pé wọ́n ti fòróró yan Dáfídì ṣe ọba lórí Ísírẹ́lì,+ gbogbo àwọn Filísínì bẹ̀rẹ̀ sí í wá Dáfídì.+ Bí Dáfídì ṣe gbọ́ báyìí, ó lọ sí ibi ààbò.+ 2 Sámúẹ́lì 5:22 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 22 Nígbà tó yá, àwọn Filísínì tún wá, wọ́n sì dúró káàkiri Àfonífojì* Réfáímù.+
17 Nígbà tí àwọn Filísínì gbọ́ pé wọ́n ti fòróró yan Dáfídì ṣe ọba lórí Ísírẹ́lì,+ gbogbo àwọn Filísínì bẹ̀rẹ̀ sí í wá Dáfídì.+ Bí Dáfídì ṣe gbọ́ báyìí, ó lọ sí ibi ààbò.+