-
Jẹ́nẹ́sísì 14:5Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
-
-
5 Torí náà, ní ọdún kẹrìnlá, Kedoláómà àti àwọn ọba tó wà pẹ̀lú rẹ̀ wá, wọ́n sì ṣẹ́gun Réfáímù ní Aṣiteroti-kánáímù, wọ́n ṣẹ́gun Súsímù ní Hámù, Émímù+ ní Ṣafe-kíríátáímù,
-