Sáàmù 18:2, 3 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 2 Jèhófà ni àpáta gàǹgà mi àti odi ààbò mi àti Ẹni tó ń gbà mí sílẹ̀.+ Ọlọ́run mi ni àpáta mi,+ ẹni tí mo fi ṣe ibi ààbò,Apata mi àti ìwo* ìgbàlà mi,* ibi ààbò mi.*+ 3 Mo ké pe Jèhófà, ẹni tí ìyìn yẹ,Yóò sì gbà mí lọ́wọ́ àwọn ọ̀tá mi.+
2 Jèhófà ni àpáta gàǹgà mi àti odi ààbò mi àti Ẹni tó ń gbà mí sílẹ̀.+ Ọlọ́run mi ni àpáta mi,+ ẹni tí mo fi ṣe ibi ààbò,Apata mi àti ìwo* ìgbàlà mi,* ibi ààbò mi.*+ 3 Mo ké pe Jèhófà, ẹni tí ìyìn yẹ,Yóò sì gbà mí lọ́wọ́ àwọn ọ̀tá mi.+