-
2 Sámúẹ́lì 22:2-4Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
-
-
2 Ó sọ pé:
“Jèhófà ni àpáta gàǹgà mi àti odi ààbò+ mi àti Ẹni tó ń gbà mí sílẹ̀.+
3 Ọlọ́run mi ni àpáta+ mi, ẹni tí mo fi ṣe ibi ààbò,
Apata+ mi àti ìwo* ìgbàlà mi,* ibi ààbò+ mi,*
Àti ibi tí mo lè sá sí,+ olùgbàlà+ mi; ìwọ tí o gbà mí lọ́wọ́ àwọn oníwà ipá.
4 Mo ké pe Jèhófà, ẹni tí ìyìn yẹ,
Yóò sì gbà mí lọ́wọ́ àwọn ọ̀tá mi.
-