Sáàmù 35:2 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 2 Gbé asà* rẹ àti apata ńlá,+Kí o sì dìde láti gbèjà mi.+ Sáàmù 91:4 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 4 Yóò fi àwọn ìyẹ́ tó fi ń fò bò ọ́,*Wàá sì fi abẹ́ ìyẹ́ apá rẹ̀ ṣe ibi ààbò.+ Òtítọ́ rẹ̀+ yóò jẹ́ apata+ ńlá àti odi* ààbò.
4 Yóò fi àwọn ìyẹ́ tó fi ń fò bò ọ́,*Wàá sì fi abẹ́ ìyẹ́ apá rẹ̀ ṣe ibi ààbò.+ Òtítọ́ rẹ̀+ yóò jẹ́ apata+ ńlá àti odi* ààbò.