-
Diutarónómì 32:11Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
-
-
11 Bí ẹyẹ idì ṣe ń ru ìtẹ́ rẹ̀ sókè,
Tó ń rá bàbà lórí àwọn ọmọ rẹ̀ tó ṣẹ̀ṣẹ̀ gúnyẹ̀ẹ́,
Tó ń na àwọn ìyẹ́ rẹ̀ jáde láti fi gbé wọn,
Tó ń gbé wọn sórí apá+ rẹ̀,
-