ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍNTÁNẸ́Ẹ̀TÌ ti Watchtower
ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍŃTÁNẸ́Ẹ̀TÌ
ti Watchtower
Yorùbá
ọ́
  • ẹ
  • ọ
  • ṣ
  • ń
  • ẹ́
  • ẹ̀
  • ọ́
  • ọ̀
  • BÍBÉLÌ
  • ÌTẸ̀JÁDE
  • ÌPÀDÉ
  • 1 Sámúẹ́lì 18:20
    Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
    • 20 Míkálì, ọmọbìnrin Sọ́ọ̀lù,+ nífẹ̀ẹ́ Dáfídì gan-an, wọ́n sọ fún Sọ́ọ̀lù nípa rẹ̀, inú rẹ̀ sì dùn sí i.

  • 1 Sámúẹ́lì 19:11
    Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
    • 11 Lẹ́yìn náà, Sọ́ọ̀lù rán àwọn òjíṣẹ́ sí ilé Dáfídì láti máa ṣọ́ ọ, kí wọ́n sì pa á ní àárọ̀ ọjọ́ kejì,+ ṣùgbọ́n Míkálì ìyàwó Dáfídì sọ fún un pé: “Tí o kò bá sá lọ* ní òru òní, wọ́n á pa ọ́ kó tó dọ̀la.”

  • 1 Kíróníkà 15:29
    Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
    • 29 Àmọ́ nígbà tí àpótí májẹ̀mú Jèhófà wọ Ìlú Dáfídì,+ Míkálì,+ ọmọbìnrin Sọ́ọ̀lù, bojú wolẹ̀ lójú fèrèsé,* ó rí Ọba Dáfídì tó ń jó sọ́tùn-ún sósì, tó sì ń ṣayẹyẹ; ó wá bẹ̀rẹ̀ sí í pẹ̀gàn rẹ̀ nínú ọkàn rẹ̀.+

Yorùbá Publications (1987-2025)
Jáde
Wọlé
  • Yorùbá
  • Fi Ráńṣẹ́
  • Èyí tí mo fẹ́ràn jù
  • Copyright © 2025 Watch Tower Bible and Tract Society of Pennsylvania
  • Àdéhùn Nípa Lílò
  • Òfin
  • Ètò Nípa Ìsọfúnni Rẹ
  • JW.ORG
  • Wọlé
Fi Ráńṣẹ́