ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍNTÁNẸ́Ẹ̀TÌ ti Watchtower
ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍŃTÁNẸ́Ẹ̀TÌ
ti Watchtower
Yorùbá
ọ́
  • ẹ
  • ọ
  • ṣ
  • ń
  • ẹ́
  • ẹ̀
  • ọ́
  • ọ̀
  • BÍBÉLÌ
  • ÌTẸ̀JÁDE
  • ÌPÀDÉ
  • 1 Sámúẹ́lì 14:49
    Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
    • 49 Àwọn ọmọkùnrin Sọ́ọ̀lù ni Jónátánì, Íṣífì àti Maliki-ṣúà.+ Ó ní ọmọbìnrin méjì; èyí ẹ̀gbọ́n ń jẹ́ Mérábù,+ àbúrò rẹ̀ sì ń jẹ́ Míkálì.+

  • 1 Sámúẹ́lì 19:11
    Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
    • 11 Lẹ́yìn náà, Sọ́ọ̀lù rán àwọn òjíṣẹ́ sí ilé Dáfídì láti máa ṣọ́ ọ, kí wọ́n sì pa á ní àárọ̀ ọjọ́ kejì,+ ṣùgbọ́n Míkálì ìyàwó Dáfídì sọ fún un pé: “Tí o kò bá sá lọ* ní òru òní, wọ́n á pa ọ́ kó tó dọ̀la.”

  • 1 Sámúẹ́lì 25:44
    Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
    • 44 Àmọ́ Sọ́ọ̀lù ti fi Míkálì+ ọmọ rẹ̀ tó jẹ́ ìyàwó Dáfídì fún Pálítì+ ọmọ Láíṣì, tó wá láti Gálímù.

  • 2 Sámúẹ́lì 3:13
    Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
    • 13 Ó fèsì pé: “Ó dáa! Màá bá ọ dá májẹ̀mú. Ohun kan ṣoṣo tí màá béèrè lọ́wọ́ rẹ ni pé, o ò gbọ́dọ̀ fojú kàn mí, àfi tí o bá mú Míkálì,+ ọmọ Sọ́ọ̀lù dání, nígbà tí o bá ń bọ̀ wá rí mi.”

  • 2 Sámúẹ́lì 6:16
    Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
    • 16 Àmọ́ nígbà tí Àpótí Jèhófà wọ Ìlú Dáfídì, Míkálì,+ ọmọbìnrin Sọ́ọ̀lù, bojú wolẹ̀ láti ojú fèrèsé,* ó rí Ọba Dáfídì tó ń fò sókè, tó ń jó yí ká níwájú Jèhófà; ó sì bẹ̀rẹ̀ sí í pẹ̀gàn rẹ̀ nínú ọkàn rẹ̀.+

Yorùbá Publications (1987-2025)
Jáde
Wọlé
  • Yorùbá
  • Fi Ráńṣẹ́
  • Èyí tí mo fẹ́ràn jù
  • Copyright © 2025 Watch Tower Bible and Tract Society of Pennsylvania
  • Àdéhùn Nípa Lílò
  • Òfin
  • Ètò Nípa Ìsọfúnni Rẹ
  • JW.ORG
  • Wọlé
Fi Ráńṣẹ́