ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍNTÁNẸ́Ẹ̀TÌ ti Watchtower
ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍŃTÁNẸ́Ẹ̀TÌ
ti Watchtower
Yorùbá
ọ́
  • ẹ
  • ọ
  • ṣ
  • ń
  • ẹ́
  • ẹ̀
  • ọ́
  • ọ̀
  • BÍBÉLÌ
  • ÌTẸ̀JÁDE
  • ÌPÀDÉ
  • 1 Sámúẹ́lì 28:6
    Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
    • 6 Bí Sọ́ọ̀lù tilẹ̀ ń wádìí lọ́dọ̀ Jèhófà,+ Jèhófà kò dá a lóhùn rárá, ì báà jẹ́ nípasẹ̀ àlá tàbí nípasẹ̀ Úrímù  + tàbí àwọn wòlíì.

  • Òwe 1:28
    Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
    • 28 Ní àkókò yẹn, wọ́n á máa pè mí, àmọ́ mi ò ní dáhùn;

      Wọ́n á máa fi ìtara wá mi, àmọ́ wọn ò ní rí mi,+

  • Àìsáyà 1:15
    Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
    • 15 Tí ẹ bá sì tẹ́ ọwọ́ yín,

      Mò ń fojú mi pa mọ́ fún yín.+

      Bí ẹ tiẹ̀ ń gbàdúrà púpọ̀,+

      Mi ò gbọ́ àdúrà yín;+

      Ẹ̀jẹ̀ kún ọwọ́ yín.+

  • Míkà 3:4
    Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
    •  4 Ní àkókò yẹn, wọ́n á ké pe Jèhófà pé kó ran àwọn lọ́wọ́,

      Àmọ́ kò ní dá wọn lóhùn.

      Ó máa fi ojú rẹ̀ pa mọ́ fún wọn ní àkókò yẹn,+

      Torí ìwà burúkú wọn.+

Yorùbá Publications (1987-2025)
Jáde
Wọlé
  • Yorùbá
  • Fi Ráńṣẹ́
  • Èyí tí mo fẹ́ràn jù
  • Copyright © 2025 Watch Tower Bible and Tract Society of Pennsylvania
  • Àdéhùn Nípa Lílò
  • Òfin
  • Ètò Nípa Ìsọfúnni Rẹ
  • JW.ORG
  • Wọlé
Fi Ráńṣẹ́