2 Sámúẹ́lì 8:3 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 3 Dáfídì ṣẹ́gun Hadadésà ọmọ Réhóbù ọba Sóbà+ bí ó ṣe ń lọ láti gba àkóso rẹ̀ pa dà ní odò Yúfírétì.+ Sáàmù 2:8 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 8 Béèrè lọ́wọ́ mi, màá fi àwọn orílẹ̀-èdè ṣe ogún fún ọMàá sì fi gbogbo ìkángun ayé ṣe ohun ìní fún ọ.+ Sáàmù 60:8 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 8 Móábù ni bàsíà tí mo fi ń wẹ ẹsẹ̀.+ Orí Édómù ni màá ju bàtà mi sí.+ Màá kígbe ìṣẹ́gun lórí Filísíà.”+
3 Dáfídì ṣẹ́gun Hadadésà ọmọ Réhóbù ọba Sóbà+ bí ó ṣe ń lọ láti gba àkóso rẹ̀ pa dà ní odò Yúfírétì.+
8 Béèrè lọ́wọ́ mi, màá fi àwọn orílẹ̀-èdè ṣe ogún fún ọMàá sì fi gbogbo ìkángun ayé ṣe ohun ìní fún ọ.+
8 Móábù ni bàsíà tí mo fi ń wẹ ẹsẹ̀.+ Orí Édómù ni màá ju bàtà mi sí.+ Màá kígbe ìṣẹ́gun lórí Filísíà.”+