2 Sámúẹ́lì 5:12 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 12 Dáfídì wá mọ̀ pé Jèhófà ti fìdí ìjọba òun múlẹ̀ lórí Ísírẹ́lì+ àti pé ó ti gbé ìjọba òun ga+ nítorí àwọn èèyàn Rẹ̀ Ísírẹ́lì.+ 2 Sámúẹ́lì 7:9 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 9 Màá wà pẹ̀lú rẹ níbikíbi tí o bá lọ,+ màá sì mú* gbogbo àwọn ọ̀tá rẹ kúrò níwájú rẹ;+ màá jẹ́ kí orúkọ rẹ lókìkí gan-an+ bí orúkọ àwọn ẹni ńlá tó wà láyé.
12 Dáfídì wá mọ̀ pé Jèhófà ti fìdí ìjọba òun múlẹ̀ lórí Ísírẹ́lì+ àti pé ó ti gbé ìjọba òun ga+ nítorí àwọn èèyàn Rẹ̀ Ísírẹ́lì.+
9 Màá wà pẹ̀lú rẹ níbikíbi tí o bá lọ,+ màá sì mú* gbogbo àwọn ọ̀tá rẹ kúrò níwájú rẹ;+ màá jẹ́ kí orúkọ rẹ lókìkí gan-an+ bí orúkọ àwọn ẹni ńlá tó wà láyé.