ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍNTÁNẸ́Ẹ̀TÌ ti Watchtower
ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍŃTÁNẸ́Ẹ̀TÌ
ti Watchtower
Yorùbá
ọ́
  • ẹ
  • ọ
  • ṣ
  • ń
  • ẹ́
  • ẹ̀
  • ọ́
  • ọ̀
  • BÍBÉLÌ
  • ÌTẸ̀JÁDE
  • ÌPÀDÉ
  • 2 Sámúẹ́lì 15:31
    Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
    • 31 Dáfídì gbọ́ pé: “Áhítófẹ́lì wà lára àwọn tí ó dìtẹ̀+ pẹ̀lú Ábúsálómù.”+ Ni Dáfídì bá sọ pé: “Jèhófà,+ jọ̀wọ́ sọ ìmọ̀ràn* Áhítófẹ́lì di ti òmùgọ̀!”+

  • 2 Sámúẹ́lì 16:23
    Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
    • 23 Láyé ìgbà yẹn, ńṣe ni wọ́n máa ń wo ìmọ̀ràn tí Áhítófẹ́lì+ bá fúnni bí ọ̀rọ̀ tí Ọlọ́run tòótọ́ sọ.* Irú ojú yẹn náà sì ni Dáfídì àti Ábúsálómù fi máa ń wo gbogbo ìmọ̀ràn Áhítófẹ́lì.

  • 2 Sámúẹ́lì 17:23
    Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
    • 23 Nígbà tí Áhítófẹ́lì rí i pé wọn ò tẹ̀ lé ìmọ̀ràn òun, ó de ohun tí wọ́n fi ń jókòó mọ́ kẹ́tẹ́kẹ́tẹ́,* ó sì lọ sí ilé rẹ̀ ní ìlú rẹ̀.+ Lẹ́yìn tó ti sọ ohun tí agbo ilé rẹ̀+ máa ṣe, ó pokùn so.*+ Torí náà, ó kú, wọ́n sì sin ín sí ibi tí wọ́n sin àwọn baba ńlá rẹ̀ sí.

  • 1 Kíróníkà 27:33
    Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
    • 33 Áhítófẹ́lì+ jẹ́ agbani-nímọ̀ràn ọba, Húṣáì+ tó jẹ́ Áríkì sì ni ọ̀rẹ́* ọba.

Yorùbá Publications (1987-2025)
Jáde
Wọlé
  • Yorùbá
  • Fi Ráńṣẹ́
  • Èyí tí mo fẹ́ràn jù
  • Copyright © 2025 Watch Tower Bible and Tract Society of Pennsylvania
  • Àdéhùn Nípa Lílò
  • Òfin
  • Ètò Nípa Ìsọfúnni Rẹ
  • JW.ORG
  • Wọlé
Fi Ráńṣẹ́