2 Sámúẹ́lì 4:10 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 10 nígbà tí ẹnì kan wá sọ fún mi pé, ‘Wò ó, Sọ́ọ̀lù ti kú,’+ ó rò pé ìròyìn ayọ̀ lòun mú wá fún mi, mo gbá a mú, mo sì pa á+ ní Síkílágì. Nǹkan tí mo fi san èrè iṣẹ́ tó wá jẹ́ nìyẹn!
10 nígbà tí ẹnì kan wá sọ fún mi pé, ‘Wò ó, Sọ́ọ̀lù ti kú,’+ ó rò pé ìròyìn ayọ̀ lòun mú wá fún mi, mo gbá a mú, mo sì pa á+ ní Síkílágì. Nǹkan tí mo fi san èrè iṣẹ́ tó wá jẹ́ nìyẹn!