-
2 Sámúẹ́lì 16:13Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
-
-
13 Torí náà, Dáfídì àti àwọn ọkùnrin rẹ̀ ń lọ lójú ọ̀nà bí Ṣíméì ṣe ń rìn lẹ́gbẹ̀ẹ́ òkè náà, tí ó sì ń lọ lẹ́gbẹ̀ẹ́ Dáfídì, ó ń ṣépè,+ ó ń ju òkúta, ó sì ń da iyẹ̀pẹ̀ lù wọ́n.
-