1 Àwọn Ọba 4:21 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 21 Sólómọ́nì ṣàkóso gbogbo àwọn ìjọba láti Odò*+ dé ilẹ̀ àwọn Filísínì àti títí dé ààlà Íjíbítì. Wọ́n ń mú ìṣákọ́lẹ̀* wá, wọ́n sì ń sin Sólómọ́nì ní gbogbo ọjọ́ ayé rẹ̀.+ Oníwàásù 7:11 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 11 Ọgbọ́n pẹ̀lú ogún jẹ́ ohun tó dáa, ó sì jẹ́ àǹfààní fún àwọn tó ń rí ìmọ́lẹ̀ ọjọ́.*
21 Sólómọ́nì ṣàkóso gbogbo àwọn ìjọba láti Odò*+ dé ilẹ̀ àwọn Filísínì àti títí dé ààlà Íjíbítì. Wọ́n ń mú ìṣákọ́lẹ̀* wá, wọ́n sì ń sin Sólómọ́nì ní gbogbo ọjọ́ ayé rẹ̀.+