2 Sámúẹ́lì 11:3 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 3 Dáfídì rán ẹnì kan láti lọ wádìí nípa obìnrin náà, ẹni náà sì wá jábọ̀ pé: “Ṣebí Bátí-ṣébà+ ọmọ Élíámù+ ìyàwó Ùráyà+ ọmọ Hétì ni.”+ 2 Sámúẹ́lì 11:27 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 27 Gbàrà tí àkókò ọ̀fọ̀ náà parí, Dáfídì ránṣẹ́ sí i, ó mú un wá sí ilé rẹ̀, ó di ìyàwó rẹ̀,+ ó sì bí ọmọkùnrin kan fún un. Àmọ́ ohun tí Dáfídì ṣe yìí bí Jèhófà nínú* gan-an.+
3 Dáfídì rán ẹnì kan láti lọ wádìí nípa obìnrin náà, ẹni náà sì wá jábọ̀ pé: “Ṣebí Bátí-ṣébà+ ọmọ Élíámù+ ìyàwó Ùráyà+ ọmọ Hétì ni.”+
27 Gbàrà tí àkókò ọ̀fọ̀ náà parí, Dáfídì ránṣẹ́ sí i, ó mú un wá sí ilé rẹ̀, ó di ìyàwó rẹ̀,+ ó sì bí ọmọkùnrin kan fún un. Àmọ́ ohun tí Dáfídì ṣe yìí bí Jèhófà nínú* gan-an.+