2 Sámúẹ́lì 8:16 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 16 Jóábù+ ọmọ Seruáyà ni olórí àwọn ọmọ ogun, Jèhóṣáfátì+ ọmọ Áhílúdù sì ni akọ̀wé ìrántí. 2 Sámúẹ́lì 20:24 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 24 Ádórámù+ ni olórí àwọn tí ọba ní kó máa ṣiṣẹ́ fún òun; Jèhóṣáfátì+ ọmọ Áhílúdù sì ni akọ̀wé ìrántí.
24 Ádórámù+ ni olórí àwọn tí ọba ní kó máa ṣiṣẹ́ fún òun; Jèhóṣáfátì+ ọmọ Áhílúdù sì ni akọ̀wé ìrántí.