Nọ́ńbà 32:41 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 41 Jáírì ọmọ Mánásè lọ síbẹ̀ láti gbógun jà wọ́n, ó sì gba àwọn abúlé tí wọ́n pàgọ́ sí, ó wá pè wọ́n ní Hafotu-jáírì.*+ Diutarónómì 3:14 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 14 “Jáírì+ ọmọ Mánásè gba gbogbo agbègbè Ágóbù+ títí dé ààlà àwọn ará Géṣúrì àti àwọn ará Máákátì,+ ó sì sọ àwọn abúlé Báṣánì yẹn ní orúkọ ara rẹ̀, ìyẹn Hafotu-jáírì*+ títí di òní olónìí.
41 Jáírì ọmọ Mánásè lọ síbẹ̀ láti gbógun jà wọ́n, ó sì gba àwọn abúlé tí wọ́n pàgọ́ sí, ó wá pè wọ́n ní Hafotu-jáírì.*+
14 “Jáírì+ ọmọ Mánásè gba gbogbo agbègbè Ágóbù+ títí dé ààlà àwọn ará Géṣúrì àti àwọn ará Máákátì,+ ó sì sọ àwọn abúlé Báṣánì yẹn ní orúkọ ara rẹ̀, ìyẹn Hafotu-jáírì*+ títí di òní olónìí.