1 Àwọn Ọba 1:5 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 5 Ní àkókò yìí, Ádóníjà+ ọmọkùnrin Hágítì ń gbé ara rẹ̀ ga, ó ń sọ pé: “Èmi ló máa di ọba!” Ó ní kí wọ́n ṣe kẹ̀kẹ́ ẹṣin kan fún òun, ó kó àwọn agẹṣin jọ àti àádọ́ta (50) ọkùnrin tí á máa sáré níwájú rẹ̀.+ 1 Àwọn Ọba 1:11 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 11 Nátánì+ wá sọ fún Bátí-ṣébà,+ ìyá Sólómọ́nì+ pé: “Ṣé o kò tíì gbọ́ pé Ádóníjà+ ọmọ Hágítì ti di ọba, olúwa wa Dáfídì kò sì mọ nǹkan kan nípa rẹ̀?
5 Ní àkókò yìí, Ádóníjà+ ọmọkùnrin Hágítì ń gbé ara rẹ̀ ga, ó ń sọ pé: “Èmi ló máa di ọba!” Ó ní kí wọ́n ṣe kẹ̀kẹ́ ẹṣin kan fún òun, ó kó àwọn agẹṣin jọ àti àádọ́ta (50) ọkùnrin tí á máa sáré níwájú rẹ̀.+
11 Nátánì+ wá sọ fún Bátí-ṣébà,+ ìyá Sólómọ́nì+ pé: “Ṣé o kò tíì gbọ́ pé Ádóníjà+ ọmọ Hágítì ti di ọba, olúwa wa Dáfídì kò sì mọ nǹkan kan nípa rẹ̀?