-
Ìsíkíẹ́lì 41:6, 7Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
-
-
6 Àwọn yàrá náà ní àjà mẹ́ta, ọ̀kan wà lórí èkejì, ọgbọ̀n (30) yàrá ló sì wà nínú àjà kọ̀ọ̀kan. Ògiri tẹ́ńpìlì náà ní igun yí ká, èyí tó gbé àwọn yàrá náà dúró tó fi jẹ́ pé ohun tó gbé àwọn yàrá náà dúró kò wọnú ògiri tẹ́ńpìlì.+ 7 Àtẹ̀gùn* kan wà ní ẹ̀gbẹ́ méjèèjì tẹ́ńpìlì náà tó ń fẹ̀ sí i láti ìsàlẹ̀ lọ sókè.+ Bí èèyàn bá ṣe ń gùn ún láti àjà kan sí òmíràn ló ń fẹ̀ sí i, ó ń fẹ̀ sí i láti àjà ìsàlẹ̀ dé àjà àárín lọ sí àjà òkè.
-