-
1 Àwọn Ọba 6:10Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
-
-
10 Ó kọ́ àwọn yàrá ẹ̀gbẹ́ yí ilé náà ká,+ gíga ọ̀kọ̀ọ̀kan wọn jẹ́ ìgbọ̀nwọ́ márùn-ún, àwọn gẹdú igi kédárì ni ó sì fi mú wọn mọ́ ara ilé náà.
-