ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍNTÁNẸ́Ẹ̀TÌ ti Watchtower
ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍŃTÁNẸ́Ẹ̀TÌ
ti Watchtower
Yorùbá
ọ́
  • ẹ
  • ọ
  • ṣ
  • ń
  • ẹ́
  • ẹ̀
  • ọ́
  • ọ̀
  • BÍBÉLÌ
  • ÌTẸ̀JÁDE
  • ÌPÀDÉ
  • Ẹ́kísódù 27:9
    Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
    • 9 “Kí o ṣe àgbàlá+ àgọ́ ìjọsìn náà. Ní apá gúúsù tó dojú kọ gúúsù, kí àgbàlá náà ní àwọn aṣọ ìdábùú tí wọ́n fi aṣọ ọ̀gbọ̀* lílọ́ tó dáa ṣe, èyí tí wọ́n máa ta, kí gígùn ẹ̀gbẹ́ kan jẹ́ ọgọ́rùn-ún (100) ìgbọ̀nwọ́.+

  • 2 Kíróníkà 4:9
    Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
    • 9 Ó wá ṣe àgbàlá+ àwọn àlùfáà+ àti àgbàlá ńlá* pẹ̀lú àwọn ilẹ̀kùn àgbàlá náà,+ ó sì fi bàbà bo àwọn ilẹ̀kùn wọn.

  • 2 Kíróníkà 7:7
    Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
    • 7 Nígbà náà, Sólómọ́nì ya àárín àgbàlá tó wà níwájú ilé Jèhófà sí mímọ́, torí ibẹ̀ ló ti máa rú àwọn ẹbọ sísun+ àti àwọn apá tó lọ́ràá lára àwọn ẹbọ ìrẹ́pọ̀, nítorí pé pẹpẹ bàbà+ tí Sólómọ́nì ṣe kò lè gba àwọn ẹbọ sísun náà àti ọrẹ ọkà+ pẹ̀lú àwọn apá tó lọ́ràá.+

Yorùbá Publications (1987-2025)
Jáde
Wọlé
  • Yorùbá
  • Fi Ráńṣẹ́
  • Èyí tí mo fẹ́ràn jù
  • Copyright © 2025 Watch Tower Bible and Tract Society of Pennsylvania
  • Àdéhùn Nípa Lílò
  • Òfin
  • Ètò Nípa Ìsọfúnni Rẹ
  • JW.ORG
  • Wọlé
Fi Ráńṣẹ́