Ẹ́kísódù 40:8 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 8 Kí o wá ṣe àgbàlá+ yí i ká, kí o sì ta aṣọ*+ sí ẹnu ọ̀nà àgbàlá náà. 1 Àwọn Ọba 6:36 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 36 Ó fi òkúta gbígbẹ́ kọ́ ipele mẹ́ta ògiri àgbàlá inú,+ lẹ́yìn náà wọ́n gbé ipele kan ìtì igi kédárì+ lé e.
36 Ó fi òkúta gbígbẹ́ kọ́ ipele mẹ́ta ògiri àgbàlá inú,+ lẹ́yìn náà wọ́n gbé ipele kan ìtì igi kédárì+ lé e.