1 Àwọn Ọba 7:12 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 12 Ọ̀wọ́ mẹ́ta òkúta gbígbẹ́ àti ọ̀wọ́ kan ìtì igi kédárì yí àgbàlá ńlá náà ká bíi ti àgbàlá inú+ ilé Jèhófà àti ibi àbáwọlé* ilé náà.+
12 Ọ̀wọ́ mẹ́ta òkúta gbígbẹ́ àti ọ̀wọ́ kan ìtì igi kédárì yí àgbàlá ńlá náà ká bíi ti àgbàlá inú+ ilé Jèhófà àti ibi àbáwọlé* ilé náà.+