7 Nígbà náà, Sólómọ́nì ya àárín àgbàlá tó wà níwájú ilé Jèhófà sí mímọ́, torí ibẹ̀ ló ti máa rú àwọn ẹbọ sísun+ àti àwọn apá tó lọ́ràá lára àwọn ẹbọ ìrẹ́pọ̀, nítorí pé pẹpẹ bàbà+ tí Sólómọ́nì ṣe kò lè gba àwọn ẹbọ sísun náà àti ọrẹ ọkà+ pẹ̀lú àwọn apá tó lọ́ràá.+