-
1 Àwọn Ọba 6:32Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
-
-
32 Igi ahóyaya ni wọ́n fi ṣe àwọn ilẹ̀kùn méjèèjì, ó gbẹ́ àwọn kérúbù, igi ọ̀pẹ àti ìtànná òdòdó sára wọn, ó sì fi wúrà bò wọ́n; ó fi òòlù tẹ wúrà náà mọ́ àwọn kérúbù àti àwọn igi ọ̀pẹ náà lára.
-