Ìsíkíẹ́lì 41:17, 18 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 17 Ó wọn òkè ẹnu ọ̀nà náà, inú tẹ́ńpìlì, ìta àti gbogbo ògiri yí ká. 18 Wọ́n gbẹ́ àwòrán àwọn kérúbù+ àti igi ọ̀pẹ+ sára rẹ̀, àwòrán igi ọ̀pẹ kan wà láàárín kérúbù méjì, kérúbù kọ̀ọ̀kan sì ní ojú méjì.
17 Ó wọn òkè ẹnu ọ̀nà náà, inú tẹ́ńpìlì, ìta àti gbogbo ògiri yí ká. 18 Wọ́n gbẹ́ àwòrán àwọn kérúbù+ àti igi ọ̀pẹ+ sára rẹ̀, àwòrán igi ọ̀pẹ kan wà láàárín kérúbù méjì, kérúbù kọ̀ọ̀kan sì ní ojú méjì.