-
1 Àwọn Ọba 7:46Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
-
-
46 Agbègbè Jọ́dánì ni ọba ti rọ wọ́n nínú ohun tó fi amọ̀ ṣe, láàárín Súkótù àti Sárétánì.
-
-
2 Kíróníkà 4:3Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
-
-
3 Àwọn iṣẹ́ ọnà tó rí bí akèrègbè+ wà nísàlẹ̀ rẹ̀ yí ká, mẹ́wàá nínú ìgbọ̀nwọ́ kan, wọ́n yí Òkun náà po. Àwọn iṣẹ́ ọnà tó rí bí akèrègbè náà wà ní ìlà méjì, ó sì ṣe é mọ́ ọn lára.
-