Ẹ́kísódù 20:24 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 24 Fi erùpẹ̀ mọ pẹpẹ fún mi, kí o sì rú àwọn ẹbọ sísun rẹ lórí rẹ̀, pẹ̀lú àwọn ẹbọ ìrẹ́pọ̀* rẹ, agbo ẹran rẹ àti ọ̀wọ́ ẹran rẹ. Gbogbo ibi tí mo bá ti mú kí wọ́n rántí orúkọ mi+ ni màá ti wá bá ọ, tí màá sì bù kún ọ. 2 Sámúẹ́lì 7:13 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 13 Òun ló máa kọ́ ilé fún orúkọ mi,+ màá sì fìdí ìtẹ́ ìjọba rẹ̀ múlẹ̀ títí láé.+
24 Fi erùpẹ̀ mọ pẹpẹ fún mi, kí o sì rú àwọn ẹbọ sísun rẹ lórí rẹ̀, pẹ̀lú àwọn ẹbọ ìrẹ́pọ̀* rẹ, agbo ẹran rẹ àti ọ̀wọ́ ẹran rẹ. Gbogbo ibi tí mo bá ti mú kí wọ́n rántí orúkọ mi+ ni màá ti wá bá ọ, tí màá sì bù kún ọ.