ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍNTÁNẸ́Ẹ̀TÌ ti Watchtower
ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍŃTÁNẸ́Ẹ̀TÌ
ti Watchtower
Yorùbá
ọ́
  • ẹ
  • ọ
  • ṣ
  • ń
  • ẹ́
  • ẹ̀
  • ọ́
  • ọ̀
  • BÍBÉLÌ
  • ÌTẸ̀JÁDE
  • ÌPÀDÉ
  • 1 Sámúẹ́lì 10:1
    Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
    • 10 Ìgbà náà ni Sámúẹ́lì mú ṣágo* òróró, ó sì da òróró inú rẹ̀ sórí Sọ́ọ̀lù.+ Ó fi ẹnu kò ó lẹ́nu, ó sì sọ pé: “Ǹjẹ́ Jèhófà kò ti fòróró yàn ọ́ ṣe aṣáájú+ lórí ogún rẹ̀?+

  • 1 Sámúẹ́lì 10:24
    Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
    • 24 Sámúẹ́lì sọ fún gbogbo àwọn èèyàn náà pé: “Ṣé ẹ rí ẹni tí Jèhófà yàn,+ pé kò sí ẹnì kankan tó dà bíi rẹ̀ láàárín gbogbo èèyàn?” Gbogbo àwọn èèyàn náà bẹ̀rẹ̀ sí í kígbe pé: “Kí ẹ̀mí ọba ó gùn o!”

  • 2 Sámúẹ́lì 15:10
    Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
    • 10 Ábúsálómù wá rán àwọn amí sí gbogbo ẹ̀yà Ísírẹ́lì pé: “Gbàrà tí ẹ bá gbọ́ ìró ìwo, kí ẹ kéde pé, ‘Ábúsálómù ti di ọba ní Hébúrónì!’”+

  • 2 Àwọn Ọba 11:12
    Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
    • 12 Lẹ́yìn náà Jèhóádà mú ọmọ ọba+ jáde, ó fi adé* dé e, ó si fi Ẹ̀rí*+ sí i lórí, wọ́n fi jọba, wọ́n sì fòróró yàn án. Wọ́n bẹ̀rẹ̀ sí í pàtẹ́wọ́, wọ́n sì ń sọ pé: “Kí ẹ̀mí ọba ó gùn o!”+

Yorùbá Publications (1987-2025)
Jáde
Wọlé
  • Yorùbá
  • Fi Ráńṣẹ́
  • Èyí tí mo fẹ́ràn jù
  • Copyright © 2025 Watch Tower Bible and Tract Society of Pennsylvania
  • Àdéhùn Nípa Lílò
  • Òfin
  • Ètò Nípa Ìsọfúnni Rẹ
  • JW.ORG
  • Wọlé
Fi Ráńṣẹ́