5 Tí ẹ bá ṣègbọràn sí ohùn mi délẹ̀délẹ̀, tí ẹ sì pa májẹ̀mú mi mọ́, ó dájú pé ẹ ó di ohun ìní mi pàtàkì* nínú gbogbo èèyàn,+ torí gbogbo ayé jẹ́ tèmi.+
26 Mo bẹ̀rẹ̀ sí í bẹ Jèhófà, mo sì sọ pé, ‘Jèhófà Olúwa Ọba Aláṣẹ, má pa àwọn èèyàn rẹ run. Ohun ìní* rẹ ni wọ́n jẹ́,+ àwọn tí o fi títóbi rẹ rà pa dà, tí o sì fi ọwọ́ agbára mú kúrò ní Íjíbítì.+