-
2 Kíróníkà 8:17, 18Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
-
-
17 Ìgbà náà ni Sólómọ́nì lọ sí Esioni-gébérì+ àti sí Élótì+ ní èbúté òkun tó wà ní ilẹ̀ Édómù.+ 18 Hírámù+ fi àwọn ọkọ̀ òkun àti àwọn òṣìṣẹ́ ọkọ̀ òkun tó mọṣẹ́ ránṣẹ́ sí Sólómọ́nì nípasẹ̀ àwọn ìránṣẹ́ rẹ̀. Wọ́n bá àwọn ìránṣẹ́ Sólómọ́nì lọ sí Ófírì,+ wọ́n sì kó ọgọ́rùn-ún mẹ́rin ó lé àádọ́ta (450) tálẹ́ńtì* wúrà+ láti ibẹ̀ wá fún Ọba Sólómọ́nì.+
-