14 Sólómọ́nì ń kó kẹ̀kẹ́ ẹṣin àti ẹṣin jọ;* ó ní ẹgbẹ̀rún kan ó lé ọgọ́rùn-ún mẹ́rin (1,400) kẹ̀kẹ́ ẹṣin àti ẹgbẹ̀rún méjìlá (12,000) ẹṣin,*+ ó sì kó wọn sí àwọn ìlú kẹ̀kẹ́ ẹṣin+ àti sí tòsí ọba ní Jerúsálẹ́mù.+
25 Sólómọ́nì ní ẹgbẹ̀rún mẹ́rin (4,000) ilé ẹṣin fún àwọn ẹṣin àti kẹ̀kẹ́ ẹṣin rẹ̀, ó sì ní ẹgbẹ̀rún méjìlá (12,000) ẹṣin,*+ ó kó wọn sí àwọn ìlú kẹ̀kẹ́ ẹṣin àti sí tòsí ọba ní Jerúsálẹ́mù.+