2 Sámúẹ́lì 3:27 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 27 Nígbà tí Ábínérì pa dà sí Hébúrónì,+ Jóábù mú un wọnú ibì kan lẹ́gbẹ̀ẹ́ ẹnubodè láti bá a sọ̀rọ̀ ní ìdákọ́ńkọ́. Àmọ́, ibẹ̀ ni ó ti gún un ní ikùn, ó sì kú;+ èyí jẹ́ nítorí pé ó pa* Ásáhélì+ arákùnrin rẹ̀. 2 Sámúẹ́lì 3:30 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 30 Bí Jóábù àti Ábíṣáì+ ẹ̀gbọ́n rẹ̀ ṣe pa Ábínérì+ nítorí pé ó pa Ásáhélì àbúrò wọn ní Gíbíónì lójú ogun+ nìyẹn.
27 Nígbà tí Ábínérì pa dà sí Hébúrónì,+ Jóábù mú un wọnú ibì kan lẹ́gbẹ̀ẹ́ ẹnubodè láti bá a sọ̀rọ̀ ní ìdákọ́ńkọ́. Àmọ́, ibẹ̀ ni ó ti gún un ní ikùn, ó sì kú;+ èyí jẹ́ nítorí pé ó pa* Ásáhélì+ arákùnrin rẹ̀.
30 Bí Jóábù àti Ábíṣáì+ ẹ̀gbọ́n rẹ̀ ṣe pa Ábínérì+ nítorí pé ó pa Ásáhélì àbúrò wọn ní Gíbíónì lójú ogun+ nìyẹn.