ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍNTÁNẸ́Ẹ̀TÌ ti Watchtower
ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍŃTÁNẸ́Ẹ̀TÌ
ti Watchtower
Yorùbá
ọ́
  • ẹ
  • ọ
  • ṣ
  • ń
  • ẹ́
  • ẹ̀
  • ọ́
  • ọ̀
  • BÍBÉLÌ
  • ÌTẸ̀JÁDE
  • ÌPÀDÉ
  • 2 Sámúẹ́lì 6:7
    Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
    • 7 Ni ìbínú Jèhófà bá ru sí Úsà, Ọlọ́run tòótọ́ pa á  + níbẹ̀ nítorí ìwà àìlọ́wọ̀+ tí ó hù, ó sì kú síbẹ̀ ní ẹ̀gbẹ́ Àpótí Ọlọ́run tòótọ́.

  • 1 Àwọn Ọba 20:35, 36
    Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
    • 35 Jèhófà bá ọ̀kan lára àwọn ọmọ wòlíì* sọ̀rọ̀,+ ni ó bá sọ fún ọ̀rẹ́ rẹ̀ pé: “Jọ̀wọ́, lù mí.” Àmọ́ ọkùnrin náà kọ̀, kò lù ú. 36 Nítorí náà, ó sọ fún un pé: “Torí pé o kò ṣègbọràn sí ohùn Jèhófà, gbàrà tí o bá ti kúrò lọ́dọ̀ mi, kìnnìún yóò pa ọ.”* Lẹ́yìn tí ó kúrò lọ́dọ̀ rẹ̀, kìnnìún kan yọ sí i, ó sì pa á.

  • 2 Àwọn Ọba 17:25
    Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
    • 25 Nígbà tí wọ́n bẹ̀rẹ̀ sí í gbé ibẹ̀, wọn kò bẹ̀rù* Jèhófà. Nítorí náà, Jèhófà rán àwọn kìnnìún sáàárín wọn,+ wọ́n sì pa lára àwọn èèyàn náà.

Yorùbá Publications (1987-2025)
Jáde
Wọlé
  • Yorùbá
  • Fi Ráńṣẹ́
  • Èyí tí mo fẹ́ràn jù
  • Copyright © 2025 Watch Tower Bible and Tract Society of Pennsylvania
  • Àdéhùn Nípa Lílò
  • Òfin
  • Ètò Nípa Ìsọfúnni Rẹ
  • JW.ORG
  • Wọlé
Fi Ráńṣẹ́