-
1 Àwọn Ọba 13:21, 22Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
-
-
21 ó pe èèyàn Ọlọ́run tòótọ́ tí ó wá láti Júdà, ó sì sọ pé, “Ohun tí Jèhófà sọ nìyí: ‘Nítorí pé o kọ ìtọ́ni Jèhófà, o kò sì pa àṣẹ Jèhófà Ọlọ́run rẹ mọ́, 22 ṣùgbọ́n o pa dà lọ, kí o lè jẹun, kí o sì mu omi ní ibi tí ó sọ fún ọ pé, “Má jẹun, má sì mu omi,” wọn ò ní sin òkú rẹ sí ibi tí wọ́n sin àwọn baba ńlá rẹ+ sí.’”
-