2 Kíróníkà 13:1, 2 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 13 Ní ọdún kejìdínlógún Ọba Jèróbóámù, Ábíjà jọba lórí Júdà.+ 2 Ọdún mẹ́ta ló fi ṣàkóso ní Jerúsálẹ́mù. Orúkọ ìyá rẹ̀ ni Mikáyà+ ọmọ Úríélì láti Gíbíà.+ Ogun sì wáyé láàárín Ábíjà àti Jèróbóámù.+
13 Ní ọdún kejìdínlógún Ọba Jèróbóámù, Ábíjà jọba lórí Júdà.+ 2 Ọdún mẹ́ta ló fi ṣàkóso ní Jerúsálẹ́mù. Orúkọ ìyá rẹ̀ ni Mikáyà+ ọmọ Úríélì láti Gíbíà.+ Ogun sì wáyé láàárín Ábíjà àti Jèróbóámù.+