1 Àwọn Ọba 15:1, 2 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 15 Ní ọdún kejìdínlógún Ọba Jèróbóámù+ ọmọ Nébátì, Ábíjámù di ọba lórí Júdà.+ 2 Ọdún mẹ́ta ló fi ṣàkóso ní Jerúsálẹ́mù. Orúkọ ìyá rẹ̀ ni Máákà,+ ọmọ ọmọ Ábíṣálómù.
15 Ní ọdún kejìdínlógún Ọba Jèróbóámù+ ọmọ Nébátì, Ábíjámù di ọba lórí Júdà.+ 2 Ọdún mẹ́ta ló fi ṣàkóso ní Jerúsálẹ́mù. Orúkọ ìyá rẹ̀ ni Máákà,+ ọmọ ọmọ Ábíṣálómù.