-
Jóṣúà 18:21Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
-
-
21 Àwọn ìlú ẹ̀yà Bẹ́ńjámínì ní ìdílé-ìdílé nìyí: Jẹ́ríkò, Bẹti-hógílà, Emeki-késísì,
-
-
Jóṣúà 18:26Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
-
-
26 Mísípè, Kéfírà, Mósáhì,
-
-
Jeremáyà 40:6Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
-
-
6 Torí náà, Jeremáyà lọ sọ́dọ̀ Gẹdaláyà ọmọ Áhíkámù ní Mísípà,+ ó sì ń gbé lọ́dọ̀ rẹ̀ ní àárín àwọn èèyàn tó ṣẹ́ kù ní ilẹ̀ náà.
-